Ija Olubadan ati Ajimobi gba ibomiran yo: Oba Adetunji gbe gomina lo si kootu - toywap

toywap

......all about NEWS

Breaking News

test banner

Post Top Ad

Responsive Ads Here
Ija Olubadan ati Ajimobi gba ibomiran yo: Oba Adetunji gbe gomina lo si kootu

Ija Olubadan ati Ajimobi gba ibomiran yo: Oba Adetunji gbe gomina lo si kootu

Share This

Olubadan ti Ibadan, Oba Saliu Adetunji ti wa fihan kedere bayii pe oun kii se eye tii ke lojo ti kii ke leerun o.

O si ti fihan pe oun setan lati ba Gomina Abiola Ajimobi na a tan bi owo, iyen fifi awon eniyan mokanlelogun miiran je oba.

Olubadan se eyi nipa gbigbe gomina lo si kootu ni Ibadan.


Awon amoye ni ejo naa yoo je okan gbogi tori opo eniyan ni yoo fe mo ibi ti igi yoo wo si.

No comments:

Post a Comment

Post Bottom Ad

Responsive Ads Here

Pages