Oro Daniel Adenimokan ti kuro l’okan mi patapata – Doris Simeon. - toywap

toywap

......all about NEWS

Breaking News

test banner

Post Top Ad

Responsive Ads Here
Oro Daniel Adenimokan ti kuro l’okan mi patapata – Doris Simeon.

Oro Daniel Adenimokan ti kuro l’okan mi patapata – Doris Simeon.

Share This

Osere binrin oni tiaata kan  ti gbogbo eniyan mo si Doris Simeon ti so pe okan ati oju oun ti kuro lara baale re tele, Daniel Adenimokan, patapata.
Oun ati okunrin naa ni won fe ara won tele, to si bi omo kan fun un ko to di pe okunrin naa ja a sile, to sib a Stella Damasus lo.
Doris Simeon ti da wa lati nnkan bii odun mefa ti oro naa ti sele.
O ti wa so fun awon oniroyin pe oun ati Daniel ko tii pinya nilana ti ofin, nitori awon ko tii lo si kootu lati gba iwe ituka ti a mo si divorce.
O wa fi kun un pe, sibesibe, emi oun ti kuro lodo okunrin naa, ti oun ko tile ro oro re mo rara.
O ni odo Olorun ni okan oun wa bayii.
O ni oun ni ololufe pataki kan, sugbon oun ko tii setan lati so nipa re.

No comments:

Post a Comment

Post Bottom Ad

Responsive Ads Here

Pages